Ẹkisodu 25:23 BM

23 “Fi igi akasia kan tabili kan, kí ó gùn ní ìwọ̀n igbọnwọ meji, kí ó fẹ̀ ní ìwọ̀n igbọnwọ kan, kí ó sì ga ní ìwọ̀n igbọnwọ kan ààbọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 25

Wo Ẹkisodu 25:23 ni o tọ