33 Kí ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ẹ̀ka mẹfẹẹfa yìí ní iṣẹ́ ọnà bí òdòdó aláràbarà mẹta mẹta tí ó dàbí òdòdó alimọndi.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 25
Wo Ẹkisodu 25:33 ni o tọ