37 Ṣe fìtílà meje fún ọ̀pá fìtílà náà, kí o sì gbé wọn ka orí ọ̀pá náà ní ọ̀nà tí gbogbo wọn yóo fi kọjú siwaju.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 25
Wo Ẹkisodu 25:37 ni o tọ