Ẹkisodu 26:14 BM

14 “Lẹ́yìn náà, fi awọ àgbò tí a ṣe ní pupa, ati awọ ewúrẹ́ tí a ṣe dáradára, ṣe ìbòrí keji fún àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:14 ni o tọ