Ẹkisodu 26:17 BM

17 Kí igi kọ̀ọ̀kan ní àtẹ̀bọ̀ meji, tí wọ́n tẹ̀ bọ inú ara wọn, bẹ́ẹ̀ ni kí o ṣe gbogbo àwọn igi tí wọ́n wà ninu àgọ́ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:17 ni o tọ