Ẹkisodu 26:2 BM

2 Kí gígùn aṣọ títa kọ̀ọ̀kan jẹ́ igbọnwọ mejidinlọgbọn, kí fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ igbọnwọ mẹrin, kí àwọn aṣọ títa náà gùn bákan náà, kí wọ́n sì fẹ̀ bákan náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:2 ni o tọ