Ẹkisodu 26:25 BM

25 Gbogbo àkànpọ̀ igi yóo jẹ́ mẹjọ, ìtẹ́lẹ̀ fadaka wọn yóo sì jẹ́ mẹrindinlogun, meji meji lábẹ́ àkànpọ̀ igi kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:25 ni o tọ