Ẹkisodu 26:35 BM

35 Kí o gbé tabili kalẹ̀ ní ọwọ́ òde aṣọ títa náà, kí ọ̀pá fìtílà wà ní apá ìhà gúsù àgọ́ náà, ní òdìkejì tabili náà, kí o sì gbé tabili náà kalẹ̀ ní apá àríwá.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:35 ni o tọ