Ẹkisodu 27:14 BM

14 Aṣọ títa kan yóo wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni ẹnu ọ̀nà àgbàlá náà, yóo gùn ní igbọnwọ mẹẹdogun, yóo ní òpó mẹta ati ìtẹ́lẹ̀ mẹta.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 27

Wo Ẹkisodu 27:14 ni o tọ