Ẹkisodu 27:19 BM

19 Idẹ ni kí o fi ṣe gbogbo àwọn ohun èlò inú àgọ́ náà ati gbogbo èèkàn rẹ̀, ati gbogbo èèkàn àgbàlá náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 27

Wo Ẹkisodu 27:19 ni o tọ