4 Idẹ ni kí o fi ṣe asẹ́ ààrò rẹ̀, kí o sì ṣe òrùka idẹ mẹrin, ọ̀kọ̀ọ̀kan sí igun mẹrẹẹrin asẹ́ náà.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 27
Wo Ẹkisodu 27:4 ni o tọ