Ẹkisodu 27:9 BM

9 “Ṣe àgbàlá kan sinu àgọ́ náà. Aṣọ ọ̀gbọ̀ ni kí o fi ṣe aṣọ títa apá gúsù àgbàlá náà, kí gígùn rẹ̀ jẹ́ ọgọrun-un igbọnwọ,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 27

Wo Ẹkisodu 27:9 ni o tọ