Ẹkisodu 28:14 BM

14 ati ẹ̀wọ̀n wúrà meji tí a lọ́ pọ̀ bí okùn, kí o sì so àwọn ẹ̀wọ̀n wúrà náà mọ́ àwọn ìtẹ́lẹ̀ wúrà náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 28

Wo Ẹkisodu 28:14 ni o tọ