16 Bákan náà ni ìbú ati òòró rẹ̀ yóo rí, ìṣẹ́po meji ni yóo jẹ́, ìbú ati òòró rẹ̀ yóo sì jẹ́ ìká kọ̀ọ̀kan.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 28
Wo Ẹkisodu 28:16 ni o tọ