Ẹkisodu 28:29 BM

29 “Orúkọ àwọn ọmọ Israẹli yóo máa wà lára Aaroni, lórí ìgbàyà ìdájọ́, ní oókan àyà rẹ̀, nígbà tí ó bá wọ ibi mímọ́ lọ, fún ìrántí nígbà gbogbo níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 28

Wo Ẹkisodu 28:29 ni o tọ