Ẹkisodu 28:36 BM

36 “Fi ojúlówó wúrà ṣe ìgbátí kan kí o sì kọ àkọlé sí i gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ sí ara òrùka èdìdì, àkọlé náà nìyí: ‘Mímọ́ fún OLUWA.’

Ka pipe ipin Ẹkisodu 28

Wo Ẹkisodu 28:36 ni o tọ