12 Gbà ninu ẹ̀jẹ̀ akọ mààlúù náà, kí o fi ìka rẹ tọ́ ọ sí ara ìwo pẹpẹ, kí o sì da ìyókù rẹ̀ sí ìsàlẹ̀ pẹpẹ.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 29
Wo Ẹkisodu 29:12 ni o tọ