Ẹkisodu 29:23 BM

23 Mú burẹdi kan, àkàrà dídùn kan pẹlu òróró, ati burẹdi pẹlẹbẹ láti inú agbọ̀n burẹdi tí kò ní ìwúkàrà ninu, tí ó wà níwájú OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:23 ni o tọ