Ẹkisodu 29:28 BM

28 Yóo máa jẹ́ ìpín ìran wọn títí lae, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ Israẹli yóo ṣe máa fún àwọn alufaa lára ẹbọ alaafia wọn; ẹbọ wọn sí OLUWA ni.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:28 ni o tọ