Ẹkisodu 29:37 BM

37 Ọjọ́ meje ni o níláti fi ṣe ètùtù fún pẹpẹ, kí o sì yà á sí mímọ́, nígbà náà ni pẹpẹ náà yóo di mímọ́, ohunkohun tí ó bá sì kan pẹpẹ náà yóo di mímọ́ pẹlu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:37 ni o tọ