Ẹkisodu 29:4 BM

4 “Mú Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ àjọ, kí o sì fi omi wẹ̀ wọ́n.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:4 ni o tọ