Ẹkisodu 29:42 BM

42 Atọmọdọmọ yín yóo máa rúbọ sísun náà nígbà gbogbo lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ àjọ, níwájú OLUWA, níbi tí n óo ti máa bá yín pàdé, tí n óo sì ti máa bá yín sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:42 ni o tọ