Ẹkisodu 29:46 BM

46 Wọn yóo sì mọ̀ pé èmi ni OLUWA Ọlọrun wọn, ẹni tí ó mú wọn jáde wá láti ilẹ̀ Ijipti, kí n lè máa gbé ààrin wọn. Èmi ni OLUWA Ọlọrun wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 29

Wo Ẹkisodu 29:46 ni o tọ