2 Angẹli OLUWA farahàn án ninu ahọ́n iná láàrin ìgbẹ́; bí ó ti wò ó, ó rí i pé iná ń jó nítòótọ́, ṣugbọn igbó náà kò jóná.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 3
Wo Ẹkisodu 3:2 ni o tọ