20 Nítorí náà n óo lo agbára mi láti fi jẹ Ijipti níyà, ń óo sì ṣe iṣẹ́ ìyanu níbẹ̀, nígbà náà ni yóo tó gbà pé kí ẹ máa lọ.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 3
Wo Ẹkisodu 3:20 ni o tọ