4 Nígbà tí Ọlọrun rí i pé ó súnmọ́ ọn láti wo ohun ìyanu náà, Ọlọrun pè é láti inú igbó náà, ó ní, “Mose! Mose!”Mose dáhùn pé, “Èmi nìyí.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 3
Wo Ẹkisodu 3:4 ni o tọ