Ẹkisodu 30:18 BM

18 “Fi idẹ ṣe agbada omi kan, kí ìdí rẹ̀ náà jẹ́ idẹ, gbé e sí ààrin àgọ́ àjọ ati pẹpẹ, kí o sì bu omi sinu rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:18 ni o tọ