Ẹkisodu 30:24 BM

24 ati ẹẹdẹgbẹta (500) ìwọ̀n ṣekeli kasia, ìwọ̀n ṣekeli ilé OLUWA ni kí wọ́n lò láti wọ̀n wọ́n. Lẹ́yìn náà, mú ìwọ̀n hini ojúlówó òróró olifi kan.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:24 ni o tọ