3 Fi ojúlówó wúrà bo òkè, ati gbogbo ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ yíká, ati ìwo rẹ̀ pẹlu. Fi wúrà ṣe ìgbátí yí gbogbo etí rẹ̀ po.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 30
Wo Ẹkisodu 30:3 ni o tọ