Ẹkisodu 30:32 BM

32 ẹ kò gbọdọ̀ dà á sí ara àwọn eniyan lásán, ẹ kò sì gbọdọ̀ ṣe òróró mìíràn tí ó dàbí rẹ̀. Mímọ́ ni, ẹ sì gbọdọ̀ kà á sí mímọ́.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:32 ni o tọ