Ẹkisodu 30:6 BM

6 Gbé e sílẹ̀ lóde aṣọ títa tí ó wà lẹ́bàá àpótí ẹ̀rí, lọ́gangan iwájú ìtẹ́ àánú tí ó wà lókè àpótí ẹ̀rí náà, níbi tí n óo ti máa ba yín pàdé.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:6 ni o tọ