Ẹkisodu 30:8 BM

8 Nígbà tí ó bá ń gbé àwọn fìtílà náà sí ààyè wọn ní àṣáálẹ́, yóo máa sun turari náà pẹlu, títí lae ni yóo máa sun turari náà níwájú OLUWA ní ìrandíran yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 30

Wo Ẹkisodu 30:8 ni o tọ