14 Ọlọrun bá yí ọkàn rẹ̀ pada, kò sì ṣe ibi tí ó gbèrò láti ṣe sí àwọn eniyan náà mọ́.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 32
Wo Ẹkisodu 32:14 ni o tọ