Ẹkisodu 32:26 BM

26 Mose bá dúró ní ẹnu ọ̀nà àgọ́, ó ní, “Ẹ̀yin wo ni ẹ̀ ń ṣe ti OLUWA, ẹ máa bọ̀ lọ́dọ̀ mi.” Gbogbo àwọn ọmọ Lefi bá kóra jọ sọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:26 ni o tọ