Ẹkisodu 32:28 BM

28 Àwọn ọmọ Lefi sì ṣe gẹ́gẹ́ bí Mose ti wí, àwọn tí wọ́n kú láàrin àwọn eniyan náà tó ẹgbẹẹdogun (3,000) ọkunrin.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:28 ni o tọ