Ẹkisodu 32:31 BM

31 Mose bá pada tọ OLUWA lọ, ó ní, “Yéè! Àwọn eniyan wọnyi ti dẹ́ṣẹ̀ ńlá; wọ́n ti fi wúrà yá ère fún ara wọn;

Ka pipe ipin Ẹkisodu 32

Wo Ẹkisodu 32:31 ni o tọ