5 Nígbà tí Aaroni rí i bẹ́ẹ̀, ó tẹ́ pẹpẹ kan siwaju ère náà, ó sì kéde pé, “Ọ̀la yóo jẹ́ ọjọ́ àjọ fún OLUWA.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 32
Wo Ẹkisodu 32:5 ni o tọ