Ẹkisodu 33:13 BM

13 Nítorí náà, mo bẹ̀ ọ́, bí inú rẹ bá dùn sí mi, fi ọ̀nà rẹ hàn mí, kí n lè mọ̀ ọ́, kí ǹ sì lè bá ojurere rẹ pàdé. Sì ranti pé àwọn eniyan rẹ ni àwọn eniyan wọnyi.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:13 ni o tọ