Ẹkisodu 33:17 BM

17 OLUWA dá Mose lóhùn pé, “N óo ṣe ohun tí o wí, nítorí pé inú mi dùn sí ọ, mo sì mọ orúkọ rẹ.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 33

Wo Ẹkisodu 33:17 ni o tọ