2 N óo rán angẹli mi ṣáájú yín, n óo sì lé àwọn ará Kenaani ati àwọn ará Hamori, àwọn ará Hiti, ati àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi ati àwọn ará Jebusi jáde.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 33
Wo Ẹkisodu 33:2 ni o tọ