Ẹkisodu 34:22 BM

22 “Ẹ gbọdọ̀ máa ṣe àjọ̀dún ọ̀sẹ̀ ìkórè àkọ́so alikama ọkà yín, ati àjọ̀dún ìkójọ nígbà tí ẹ bá ń kórè nǹkan oko sinu abà ní òpin ọdún.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:22 ni o tọ