Ẹkisodu 34:25 BM

25 “Ẹ kò gbọdọ̀ fi ẹran rúbọ sí mi pẹlu ìwúkàrà, bẹ́ẹ̀ ni ohunkohun tí ẹ bá sì fi rú ẹbọ àjọ̀dún ìrékọjá kò gbọdọ̀ kù di ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:25 ni o tọ