Ẹkisodu 34:32 BM

32 Lẹ́yìn náà, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli súnmọ́ ọn, ó sì ṣe gbogbo ohun tí Ọlọrun bá a sọ lórí òkè Sinai lófin fún wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:32 ni o tọ