Ẹkisodu 37:1 BM

1 Besaleli fi igi akasia àpótí ẹ̀rí náà, gígùn rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ meji ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ kan ààbọ̀, ó sì ga ní igbọnwọ kan ààbọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 37

Wo Ẹkisodu 37:1 ni o tọ