23 Fìtílà meje ni ó ṣe fún ọ̀pá náà, ojúlówó wúrà ni ó fi ṣe ọ̀pá tí a fi ń pa iná ẹnu fìtílà.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 37
Wo Ẹkisodu 37:23 ni o tọ