Ẹkisodu 37:6 BM

6 Ó fi ojúlówó wúrà ṣe ìtẹ́ àánú, gígùn rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ meji ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ sì jẹ́ igbọnwọ kan ààbọ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 37

Wo Ẹkisodu 37:6 ni o tọ