Ẹkisodu 38:1 BM

1 Ó fi igi akasia ṣe pẹpẹ ẹbọ sísun, bákan náà ni gígùn ati fífẹ̀ pẹpẹ náà rí, wọ́n jẹ́ igbọnwọ marun-un marun-un, gíga rẹ̀ sì jẹ́ igbọnwọ mẹta.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:1 ni o tọ