Ẹkisodu 38:16 BM

16 Aṣọ funfun onílà tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ ni wọ́n fi ṣe gbogbo aṣọ títa tí ó wà ninu àgbàlá náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:16 ni o tọ