Ẹkisodu 38:21 BM

21 Ìṣirò ohun tí wọ́n lò fún kíkọ́ àgọ́ ẹ̀rí wíwà OLUWA nìyí: Mose ni ó pàṣẹ pé kí ọmọ Lefi ṣe ìṣirò àwọn ohun tí wọ́n lò lábẹ́ àkóso Itamari ọmọ Aaroni, alufaa.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:21 ni o tọ