Ẹkisodu 38:30 BM

30 Idẹ yìí ni ó lò láti ṣe ìtẹ́lẹ̀ àwọn ìlẹ̀kùn àgọ́ àjọ, ati pẹpẹ onídẹ, ati àwọn idẹ inú rẹ̀ ati gbogbo àwọn ohun èlò ibi pẹpẹ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:30 ni o tọ